Take a fresh look at your lifestyle.

Igbe Wa Yóò Máa Tẹ̀ẹ̀ Síwájú – Oníròyìn Tó Wà Lẹ́yìn Àwọn Ti Wọ́n Pa

0 211

 

Òṣìṣẹ́ àjọ Al Jazeera Media Network ti bu ẹnu àtẹ́ lù pípa tí wọ́n pa ara wọn, ìyàwó, ọmọkùnrin, ọmọbìnrin àti ọmọ ọmọkùnrin Wael Dahdouhni àárín gbùngbùn Gaza Strip.

Àwọn ará ilé Dahdouh àti Ẹbí Awad ni àdó olóró Israẹli bà ní ibùdó ogunlende -Nuseirat refugee camp.

Oníròyìn Al Jazeera ní èdè Larubawa Tamer Almisshal ti sọ pé ikú ìdílé Dahdouh, jẹ́ èrò orílẹ̀-èdè Israeli láti pa àwọn oníròyìn Palestine, pàápàá jù Dahdouh, Olóyè Gaza Bureau Al Jazeera ti Lárúbáwá, ti Almisshal n pè ni
“Ohùn ti Gaza”.

Ní ọjọ́ kọkànlá oṣù Kàrùn ún, ọdún 2022, oníròyìn Al Jazeera ilẹ̀ Larubawa, Shireen Abu Akleh ni wọ́n ta ni ìbọn láti ọwọ́ ológun Israeli nígbà tó n ṣiṣẹ́ rẹ níbi ibùdó oginlende-Jenin

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button