Take a fresh look at your lifestyle.

NPFL: Pillars Gbó Ewúro Sójú Katsina United Ní Kano

0 285

Ìjà àjákü-akátá ní láàrín Kano Pillars àti Katsina United nínú ìdíje Agbabuta NPFL bí Pillars ṣé bóri pẹ̀lú àmì ayo kàn sí odò (1- 0) nínú ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ náà.

Pillars tó pàdánù ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ àkọ́kọ́ wọ́n ṣọwọ́ Sunshine ní Akure ló gbá bọ́ọ̀lù s’àwọn ní iṣẹju kẹ́tàdínlọ́gbọn láti ẹsẹ Mustafa Ibrahim ní pápá ìṣèré
Sani Abacha.

Bó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwon àgbábọ́ọ̀lù Katsina United náà gbìyànjú gidigidi, ṣùgbọ́n àwọn adẹyinmu Kano Pillars náà dúró dọindọin bí eré náà ṣé wà sí òpin pẹ̀lú àmì ayo kàn sí odò 1-0.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button