Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Kan Gba Ààrẹ Nímọ̀ràn Láti Yan Olùyẹ̀wé Owó-wò Àgbà

0 216

Àjọ kan tí kìí se ti ijoba, Defenders of Constitutional Democracy (DCD) ti gba ààrẹ Tinubu ni ìmọ̀ràn láti yan Olùyẹ̀wé Owó-wò àgbà ijoba àpapọ̀. .

Alága ẹgbẹ́ náà, Alhaji Abdullahi Aliyu, lo sọ èyí ní Abuja.

Ó kẹ́dùn pé àyè àìsí Olùyẹ̀wé Owó-wò àgbà  tó yanrantí ti fi ààyè sílẹ láti jẹ kí ìwà jẹgúdú-jẹrá kó gbilẹ̀ ní ẹ̀ka ti Ministries, Departments and Agencies (MDAs) ti orílẹ̀-èdè yìí.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button