Take a fresh look at your lifestyle.

Amẹ́ríkà Rí Cook Islands Bí Orílẹ̀-èdè Tó Lágbára Láti Se Ìjọba – Biden

0 205

 

Amẹ́ríkà ti ri Cook Islands Bi Orile-ede tó lágbára láti se Ìjọba, Akọ̀wé àgbà ìjọba àpapọ̀, Antony Blinken sọ eyi ninu àkọsílẹ̀ kan ni ọjọ ajé.

Ààrẹ Biden sọ pé Washington rí wọn gẹ́gẹ́ bí Orílẹ̀-èdè to lagbara lati se Ìjọba àti ilu olominira, wọn yóò sì jọ ní àjọṣepọ̀ tó dán mọ́rán. Eyi yóò sí ilẹ̀kùn agbègbè indo-Pacific sile wọ́ọ́rọ́wọ́

Ìkéde yi wáyé leyin ti Biden n gbiyanju lati gba awọn Olori ni alejò sí Washington fún ìpàdé àpérò Olojo Méjì ti U.S.-Pacific Island Forum ti yóò dá lórí ipa ti ojú ọjọ́ ńkó.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button