Ìkọlú dúróònù tí Ukraine ṣé lórí àwọn agbégbé Kursk tí Russia bá ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ilé ìgbé àti àwọn ilé-iṣẹ́ kàn jẹ́, nigbati wọ́n bá méji mìíràn jẹ́ ní àgbégbé Belgorod ní ààrọ̀ ọjọ́ Ajé, Gomina agbegbe nàá sọ́.
Gẹgẹbi alaye kan ṣe sọ, ikọlu naa ko ko ipalara ba ẹnikankan, Gomina naa sọ ninu awọn alaye ọtọ lori ẹrọ Telegram.
Á ko tii mọ iwọn ikọlu ti agbegbe Kursk, eyi to wa ni aala Russia, lakoko ti a ko iroyin yii jọ.
Ukraine ko tii jade sọ pe oun kọlu agbegbe Russia kọọkan, yala ninu orilẹ-ede naa tabi awọn to gba mọra, Ṣùgbọ́n sọ laipẹ yii pe, biba awọn oun ija awọn ọmọ ogun Russia jẹ n fun awọn ni anfaani lati koju wọn.
Leave a Reply