Àkowé Ìjọba àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (SGF), Sẹnetọ George Akume, sọ pé wọ́n yòó ṣé àfíhàn ìwádìí tí wọ́n ṣé lórí ilé ìfowópámọ́ àpapọ̀ Nàìjíríà, CBN láìpẹ́ lóri ìṣákósó áìṣédeédẹ́ lójuná atí mú Orílẹ̀-èdè tẹ́síwajú.
Akume n sọrọ yii ni Apejọ ínú ile iroyin to waye ni ilu Abuja gẹgẹ bi apakan ipalẹmọ lati samisi ayẹyẹ́ Ominira ti orile-ede Naijiria ẹlẹ̀ẹ́kẹtàlélọ́gọ́ta irurẹ pe yoo jẹ ni iwọnba latari eto ọrọ-aje to dẹnu kọlẹ.

Leave a Reply