Take a fresh look at your lifestyle.

Ọgọ́ọ̀rún Ọjọ́ Ní Ọ́fìsì Àpẹrẹ Ìdàgbàsókè Fún Ìpínlẹ̀ Nasarawa – Adájọ àgbà Fún Ìpínlẹ̀ Nasarawa.

0 168

Adájọ àgbà pátápátá àti Kọmísọ́nà fún ètò ìdájọ, Labaran Magaji sọ wí pé Gómìnà Abdullahi Sule yóò mú ìpínlẹ̀ Nasarawa lo sí ìpele ìdàgbàsókè ń lá, látàrí àwọn àtúnṣe tí ó tí wáyé láàrin ọgọ́ọ̀rún Ọjọ́ tí o lo lẹnu iṣẹ́.

Adájọ àgbà náà sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí ó ń bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìkíni kú órire sí Gómìnà ni Lafia, ó gbóríyìn fún Gómìnà látàrí iṣé takuntakun rẹ.

Magaji ní ìfẹ́ Gómìnà sí àwọn ọ̀dọ́ kọ̀ kéré rárá èyí sì jẹ́ àpẹrẹ adari réré, nípa yiyan wọn sí ipò.

Ó wà rọ àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Nasarawa láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ìjọba Gómìnà sule kí o bá lè jisẹ ti ilu rán.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button