Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Fún Ọ̀rọ̀ Tó Ń Lọ Rọ Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Jẹ́ Akínkanjú .

0 226

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ tó ń lọ àti ìmọràn Lágbayé, Mohamed Idris ti pé àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti rí Orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí ohun tí kò ṣe yà sọtọ̀, O ní o jẹ Orílẹ̀-èdè ti o kún fún ibukún púpọ̀ pẹ̀lú èròngbà Ààrẹ Tinubu lórí àkọ̀ṣe iṣé ní ọ̀nà mẹ́jọ.

Mínísítà sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ìpínlẹ̀ Niger nigba ti ó ṣe ìbẹ̀wò sí àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí Ibrahim Badamosi babangida àti Abdulsalam abubakar.

Ó ní àwọn èdè tó tó Ààdọ́talérúgba a àti orísirísi àṣà èyí tí kò fí ayé gbà ìpínyà láàrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Abdulsalam abubakar pé àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ní ìrètí, sùúrù àti àtìlẹ́yìn fún ìjọba Ààrẹ Bọla Tinubu láti rí wí pé gbogbo rẹ ṣiṣẹ́ pọ̀ sí réré.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger Mohammed Umar Bago ki àwọn olóṣèlú to di ipò mú láti ìjọba ìpínlẹ̀  àti ìjọba àpapọ̀ ku órire o si rọ̀ wọn kì wọn jẹ Adarí réré.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button