Take a fresh look at your lifestyle.

Russia Sọ Pé Òún Tí Dá Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àwọn Ikọlù Ukraine Pàdà

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 231

Russia sọ pé òún tí dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìkọlù Ukraine pàdà àti pé ọgọọgọrun àwọn ọmọ ogún Ukraine ló pàdánù ẹ̀mí wọ́n, ní ìdánilójú pé irọ lásán ní Ukraine ń pá.

Russia tí ń ṣàkóso àwọn àgbègbè Ukraine kàn, pẹ̀lú Crimea èyí tó gbá ní ọdún 2014 àtí àwọn Ìlà-oòrùn àtí ati Gúsù Ukraine èyí tó gbá ìṣàkóso rẹ̀ ní ọdún 2022.

Russia sọ pé kó dín ní ẹgbẹ̀rún kàn àwọn ọmọ ogún Ukraine tó kú láàrín ọjọ́ kàn nínú ogún náà.

Ukraine tí n gbìyànjú láti wọ́nú àwọn ọmọ ogún Russia ní Gúúsù tí Ìlú Orikhiv ní ìgbìyànjú látí pín àwọn ológun Russia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button