Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ lẹyìn tí wọ́n tí búra fún gẹ́gẹ́ bí Àdélé Ààrẹ Gabon, Gen Brice Nguema, wí àwijàre ìfipágbàjọba ọsẹ tó kọjá, pé iṣé déédé ọmọ Orílẹ̀-èdè gidi ní.
Ó fá ọ̀rọ̀ ológun ní Ghana tẹ́lẹ̀ rí yọ́, tí wọ́n sì tún yan gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ, Jerry John Rawlings sọ pé: “Nígbà tí àwọn Olórí bá já àwọn ènìyàn kulẹ̀, àwọn ológun ló gbọ́dọ̀ fún wọn ní iyì àti òmìnira wọ́n.
“Àwa ọmọ-ogun ní olúgbèjà àwọn aráàlú lẹyìn ìdìbò eru.
Leave a Reply