Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Ààbò UK Jẹrìí Sí Ìfìposílẹ̀

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 277

Mínísítà Ààbò Orílẹ̀-èdè Biritiko [UK], Ben Wallace tí jẹrìí sí ìfìposílẹ̀ rẹ̀ bí Mínísítà Ààbò nínú lẹta kàn sí Rishi Sunak.

Wallace, ẹnití o ṣé ìrànlọ́wọ́ látí ṣé ìtọ́sọ́nà ìdáhùn tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì sí ikọlù Russia sí Ukraine, sọ ní oṣù tó kọjá pé òún yóò fí ipò sílẹ̀ lẹyìn ọdún mẹrin atí pé yóò kúrò bí aṣòfin nínú ìdìbò gbogbogbò orílẹ̀-èdè tí mbọ̀ fún àwọn ipò túntún mìíràn.

Ó ṣé àdéhùn àtìlẹ́yìn rẹ̀ fún ìjọba bí ó ṣé kìlọ fún ìjọba tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì látí máa ríi ààbò bí “ìnáwó làákàyè.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button