Ìgbìmọ̀ ìbáwí tí FIFA tí fún Alákóso Bọ́ọ̀lù afẹsẹgba Spain (RFEF) Luis Rubiales ní ìwé gbélé ẹ́ fún àádọ́rún ọjọ́ (90days), lórí bó ṣé fí ẹnú kó ẹnú pẹ̀lú àgbábọ́ọ̀lù Obínrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Spain Jenni Hermoso lẹyìn tí wọ́n gbá ìfé Àgbáyé FIFA Women’s World Cup.

Rubiales ní wọ́n tí n’ìrètí látí kéde ifi ipò sílẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ṣùgbọ́n dípò sọ pé òun kó ní fí ipò sílẹ̀, àtí pé RFEF halẹ ìgbésẹ òfin látí gbèjà rẹ̀ lẹ́yìn Hermoso sọ pé ifẹnukonu náà kò wù òún.
Leave a Reply