Take a fresh look at your lifestyle.

CAF Confederation Cup: Bendel Insurance Bórí ASO Chlef 1-0

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 304

Bendel Insurance FC tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí bórí ìfẹ́sẹ́wọ́nsẹ́ wọ́n pẹ̀lú ASO Chlef tí Algeria pẹ̀lú àmì ayò kàn sí odò nínú ifẹsẹwọnsẹ àkọ́kọ́ tí ìdíje CAF Confederation 2023/2024 ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ní pápá iṣere Samuel Ogbemudia, Benin, ìpínlẹ̀ Edo.

Imade Osarenkhoe tó gbá bọ́ọ̀lù wọlé ní iṣẹju Kejìlélógún látí ṣẹ́gun fún ìkọ rẹ̀ títí ipadabọ ní Oṣù Kẹjọ ọjọ́ kẹ́tadínlọ́gbọ́n 27th ní Algeria.

Àwọn àbájáde CAF Confederation Cup tí ọjọ́ Àìkú:

Kakamega Homeboyz 0-0 Al Hilal (B)

Arta/Solar7 3-0 Horseed

Ferroviario Maputo 3-0 Belle Lumiere (Walkover)

gaborone 0-1 Elgeco Plus

Bendel Insurance 1-0 ASO Chlef

Cano 1-1 FC Muza

Milo 1-1 Dreams.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button