Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ ECOWAS Yóò Se Ipàdé Pàjáwìrì Látàrí ìdìitẹ̀gbàjoba Tó Wáyé Ní Niger

0 276

 

Àjọ Economic Community of West African States (ECOWAS) ti kéde pé àwọn yóò se ìpàdé ní kiakia látàrí ọ látàrí ìdìitẹ̀gbàjoba ti Ọ̀gágun Abdourahamane Tchiani dari ni ìlú olómìnira Niger.

Ìpàdé náà yóò dá lórí ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro tó n lọ lọ́wọ́ ní ìlú olómìnira Niger. Ìpàdé náà kò ní jẹ́ aláfojúrí, yóò wáyé lori ẹrọ ayélujára ni ọjọ́ Kejìlá ọjọ́ Àbámẹ́ta.

Gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ mẹ́ẹ̀dógún lé ní ọgọ́rùn ún ni ìgbàgbọ wà pé yóò se ìpàdé náà tó dá lórí bí ọmọ ẹgbẹ́ se n lòdì sí òfin àti àṣẹ ẹgbẹ́ pàápàá jù orílẹ̀-èdè bii Mali, Guinea, Burkina Faso àti ìlú olómìnira Niger.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button