Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ẹjọ́ Sún Ìdájọ́ Síwájú Lórí Ẹjọ́Tí Obi Pè Tako Ìjáwé Olúborí Ààrẹ Tinubu

0 209

Ilé ẹjọ́ tí ó ń gbọ́ awuye-wuye lórí ìdìbò gbogbogbòò tí ó wà ní ìlú Abuja ti sún ìdájọ́ síwájú látàrí ẹjọ́ tí olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú Lp, ọgbẹni Pater Obi pè tako ìjáwé olúborí ààrẹ Tinubu .

 

Obi rọ ilé ẹjọ̀ láti  fagilé kíkéde ààrẹ Tinubu gẹ́gẹ́ bí ẹni ti o jáwé olúborí nínú ìdìbò gbogbogbòò ti o waye ni ojọ kẹẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n osù keji.

 

Alága àwọn olùgbẹ́jọ́ náà, adájọ́ Simon Tsammani, nígbà tí ó n sún ìdájọ́ náà síwájú sọ pé,  òun yóò se ìfiléde ọjọ́ tí ìdájọ́ náà yóò wáyé fún àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn.

.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button