Aya gómìnà ìpínlẹ̀ Plateau, Arábìnrin Helen Mutfwang sọ pé àlékún ti bá àṣà ìfọ́mọlọ́yàn dé ògóńgó ní ìpínlẹ̀ náà láti ìdá mọ́kàndínlógún nínú ọgọ́rùn-ún sí ìdá méjìdínlógójì nínú ọgọ́rùn-ún.
Mutfuang sọ ọ̀rọ̀ náà ní ìlú Jos, ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun níbi àyájọ́ ọ̀sẹ̀ ìfọ́mọlọ́yàn ti ọdún 2023.
Ó tẹ̀síwájú pé, bó tilẹ̀ jẹ́ pé alekun ba eto ifọmọlọyan, a tun gbọdọ gbiyanju lati mu itẹsiwaju ba eto naa nitori pe anfaani nla ni o maa n se fun iya ọmọ ati ọmọ
Leave a Reply