Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Kópa Níbi Àyájọ́ Òmìnira Ní Orílẹ̀-èdè Benin

0 195

Orílẹ̀-èdè Benin se ayẹyẹ òmìnira ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta pẹ̀lú ààbò tí ó péye àti yíyan àwọn ọmọ ológun

 

Ààrẹ Tinubu ni àlejò pàtàkì níbi ayẹyẹ náà.

 

Àwọn gómìnà márùn-ún láti orilẹ-ede Naijiria ni o peju sibi ayẹyẹ naa

Lara wọn ni: Abdulrahaman Abdulrazaq ti ipinlẹ Kwara, Babajide Sanwo-Olu ti ipinlẹ Eko, Seyi Makinde, Oyo, Dapo Abiodun Ogun, ati Mohammed Bago ti ipinlẹ Niger .

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button