Àlátákò Orílẹ̀-èdè South Africa Rọ Àwọn Olùdarí BRICS Látí Yẹ́ Ìpàdé Wọ́n Pẹ̀lú Russia
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ẹgbẹ́ àlátákò tí South Africa, EFF, rọ̀ àwọn Olùdarí China, India àti Brazil látí yàgò fún àpéjọ BRICS tí ń bọ̀ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Ààrẹ Russia, Vladimir Putin.
Nígbàtí on sọ̀rọ̀ ní àpéjọ ìrántí ọdún kẹwàá Ìdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Economic Freedom Fighters EFF, Malema takò pé Orílẹ̀-èdè America kọ́ ló rán òun láti máa takò Ààrẹ Russia, bẹ́ẹ̀ ló tún takò Ààrẹ South Africa, Cyril Ramaphosa.
Leave a Reply