Take a fresh look at your lifestyle.

Lionel Messi Tí Dì Àgbábọ́ọ̀lù Inter Miami Ní MLS

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 277

Lionel Messi ọmọ orílẹ̀-èdè Argentina tó tí Ballon d’Or méje ọtọtọ tí dì àgbábọ́ọ̀lù Major League Soccer (MLS) franchise Inter Miami nígbà tí wọ́n rá gẹ́gẹ́ bí àgbábọ́ọ̀lù tún ní ìkọ náà.

Àgbábọ́ọ̀lù Barcelona nígbà kàn rí, Messi, ní ìkọ Barcelona ní ìfẹ látí gbá pàdà sí Camp Nou, ṣùgbọ́n òfin ètò ìnáwó “Financial Fair Play” LaLiga kò jẹ́.

Inter Miami kéde àgbábọ́ọ̀lù náà gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ wọ́n lórí Twitter.

Ọmọ orílẹ̀-èdè Argentine tọ́wọ́ bọ́ ìwé fún ẹgbẹ́ kàn tó wà ìsàlẹ̀ tábìlì MLS. Messi yóò ní ànfààní látí gbá bọ́ọ̀lù fún Inter Miami CF ní Oṣù Keje, ọjọ́ kọkanlelogun nígbàtí wọ́n bá gbá ẹgbẹ́ LIGA MX Cruz Azul nínú ìdíje League Cup.

Ìdíje túntún náà ní wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní MLS tí LIGA MX yóò dá ìdíje wọ́n dúró látí Oṣù Keje ọjọ 21st – 19th Oṣù Kẹjọ, látí mọ́ ẹní tí yóò peregede fún ìdíje CONCACAF 2024.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button