Take a fresh look at your lifestyle.

Awoniyi Ní Ìrètí Láti Gbá Ìfé AFCON

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 340

Àgbábọ́ọ̀lù Super Eagles, Taiwo Awoniyi, tí pinnu láti ràn Nàìjíríà lọ́wọ́ látí gbá ìfé ẹ̀yẹ orílẹ̀-èdè Áfríkà kẹrin ní ọdún tó ń bọ́.

Nàìjíríà tó tí gbá ìfé náà rí ní ọdún 1980, 1994, àtí 2013, tí peregede látí kópa nínú ìdíje náà ní ọdún tó mbọ̀ lẹyìn tí wọ́n bórí Sierra Leone ní 3-2 ní Oṣù tó kọjá ní Monrovia, Liberia nínú ìfẹ́sẹ́wọ́nsẹ́ wọ́n.

Awoniyi pẹ̀lú ìkọ Super Eagles ní wọ́n kópa nínú ìdíje AFCON tí ọdún tó kọjá ní orílẹ̀-èdè Cameroon, níbí tí Tunisia tí ṣé ìyà wọ́n ní ìpele ẹní bá láyà, Ó ní ìgbàgbọ́ pé pẹ̀lú ìsọkan àtí ìdùnnú tó wà láàrín àwọn ẹlẹgbẹ rẹ̀ yóò jẹ́ bọ́tìnì láti gbà ìfé ẹ̀yẹ AFCON kẹrin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button