Cleverly Kìlọ Fún Àwọn Aráàlú Látí Yàgò Fún Ìkọlù Olúilé-iṣẹ́ India Ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè Gẹẹsi James Cleverly kìlọ pé ìjọba Orílẹ̀-èdè náà lòdì sí èyíkéyìí ikọlù sí Ilé-iṣẹ́ ìjọba gíga India ní Ìlú London.
Èyí wá lẹyìn ìròyìn ìwé pélébé kàn tó jáde nípa ìwọ́de fún àtìlẹ́yìn Ìpínlẹ̀ ọtọ fún àgbègbè Sikh.
“A tí jẹ́ kí o hàn sí Kọmisọna gíga tí Ilé-iṣẹ́ òkèèrè tí India sí Britain Vikram Doraiswami àtí Ìjọba tí India pé ààbò tó dájú tí wà fún àwọn oṣiṣẹ Ilé-iṣẹ́ gíga náà.”
Leave a Reply