Take a fresh look at your lifestyle.

Osimhen Dì Àgbábọ́ọ̀lù Kẹta Tó Níye Lórí Jù Ní Àgbáyé Báyìí

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 339

Àgbábọ́ọ̀lù Super Eagles Victor Osimhen tí wà ní ipò kẹta bí àgbábọ́ọ̀lù tó níye lórí jùlọ ní àgbáyé.

Èyí jẹ́ ìbámu sí àwọn ìròyìn bọ̀ọ́lù, àwọn onímọ̀ ọjà pàṣipàárọ̀ ní àgbáyé.

Àgbábọ́ọ̀lù ní ipò iwájú Napoli, Victor Osimhen wà ní ipò kẹta lẹyìn Erling Haaland àtí Kylian Mbappe lórí tábìlì òṣuwọn.

Kìí ṣé ìyàlẹ́nu pé Osimhen gbà ipò kẹta bó ṣé gbá adé Serie A Capocannoniere ní 2022/23, bó ṣé gbá àmì mẹ́rindìnlọgbọ́n 26 nínú ifẹsẹwọnsẹ mejilelọgbọn 32 tó sí ṣiṣẹ takuntakun láti gbá ìfé Scudetto fún Napoli ní ọdún mẹ́talélọgbọn.

Tún kà nípa:Osimhen Fẹ́ Gbábọ̀ọ́lù Fún Manchester United Tàbí Real Madrid – Bagni

Ní ipò kẹrin ní Harry Kane (England/Tottenham) wà pẹ̀lú ìyè tí €90m àtí ipò kẹfa ní Kolo Muani (France/Frankfurt) àti Christopher Nkunku (France/Chelsea) ní ìdíyelé €80m.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button