Òṣèré orí ìtagé orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì Idris Elba, tó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Sierra Leone tí pé fún àlàáfíà lẹyìn ìdìbò gbogbogbò ní Sierra Leone, èyítí o wáyé ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta.
O rán àwọn ọdọ létí pé ọwọ́ wọ́n ní “àgbàrá” inú ìbò yìí wà, àti pé tí wàhálà bá ṣẹ̀lẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè náà, kòní rọrùn láti tó pàdà.
Kìí ṣé àgbáyé nìkàn ló ń wò wa,” ṣùgbọ́n gbogbo Áfíríkà.
Ìdìbò ọjọ́ Àbámẹ́ta jẹ́ ẹ̀lẹ̀ẹ́kẹ́fa ní orílẹ̀-èdè náà lẹyìn ìgbà tí àwọn ológun tí gbá ìjọba ní ọdún 1992.
Leave a Reply