Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Onísòwò Ìpínlẹ̀ Nasarawa Gbóríyìn Fún Gómìnà Sule Fún kíkọ́ Ọjà Ìgbàlódé

0 265

Ẹgbẹ́ Onísòwò ìpínlẹ̀ Nasarawa ti lu Gomina Sule lọ́gọ ẹnu fún kikọ ọjà igbalode ní ijọba ìbílẹ̀ mẹta ní ìpínlẹ̀ naa.

 

Ẹgbẹ́ náà fí ọ̀rọ̀ ìdúpẹ́ léde nígbà tí ó ń se àyípadà ìwé òfin rẹ ní ìlú Lafia, olú ìlú ìpínlẹ̀ náà.

 

Nígbà ti o n sọrọ nibi ipade naa, adelé alága ẹgbẹ naa, Musa Aliyiu-Turaki sọ wipe ijọba ti o wa lóde naa ń se gugu-gudu méje, yààyà mẹfà fún awọn onisowo ní ìpínlẹ̀ naa. Lára awọn ọjà ti ijọba ti kọ́ ni, Akwanga, Keffi àti Nassarawa-Eggon. Nígbà tí iṣẹ́ sì ń lọ lọ́wọ́ ní ìjọba ìbílẹ̀ Toto ati Awe.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button