Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Yan Ààrẹ Tuntun

0 241

Ọ̀gbẹ́ni Joe Ajaero ti jáwé olúborí gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ tuntun ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

 

Ìyànsípò náà wáyé ní ìlú Abuja níbi àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ náà, ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlá irúu rẹ̀, tí wọ́n sì yan Ajaero gẹ́gẹ́ bíi adarí láìní alátakò.

 

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, Ó jẹ́jẹ̀ẹ́ láti mú ìgbáyégbádùn àwon òṣìṣẹ́ ní òkúkúdùn, Ó sì gbóríyìn fún ààrẹ ẹgbẹ́ náà tẹ́lẹ̀ rí, Ayuba Wabba fún iṣẹ́ ribiribi tí ó se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button