Take a fresh look at your lifestyle.

Kí Ilé Adúláwọ̀ Túbọ̀ Tèsíwájú Nípa kí kópa Nínú Káràkátà Lágbayé: Ààrẹ Buhari.

0 258

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti rọ àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkà gbogbo làti tèsíwájú nípa ki kópa nínú káràkátà Lágbàáyé, èyí tí yóò mú ànfààní bá àwọn orílẹ̀-èdè Àláwọdúdú.

 

Ààrẹ sọ èyí níbi ìpàdé ọkọ ojú omi tí Áfíríkà tó wàyè ní ìlú Èkó. Mínísítà fún Irinajo, Ademola Adegoroye lọ sójú ààrẹ nibi ìpàdé náà.

Ààrẹ ní nípa ki kópa nínú káràkátà yóò mú iṣé, ọrọ̀ ati didi ìṣòro àti òsìn kún.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button