Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Eko Wà Ọ̀nà Àbayọ Sí Fífi Ǹkan Ṣòfò.

0 225

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti, wá ọ̀nà Àbayọ ṣí ìṣòro fífi àwọn ohun èlò tó sì lè wúlò ṣòfò,pẹ̀lú lpò bí àyíká ṣe wa ni ìpínlẹ̀ náà, èyí tí tó mílíọ̀nù méjì le diẹ ni àwọn ohun èlò ilé tí o ń ṣègbé  lójoojúmó.

Aya Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó dọ́kítà, ìyáàfin Ibijoke Sanwo-Olu ló sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ọlọjọ mẹ́ta kan tí àwọn àjọ olómi tí ìpínlẹ̀ Èkó àti ìbáṣepọ̀ ilé iṣé Faecal Sludge ni orílẹ̀-èdè Nertherland ṣe ni ìlú Èkó.

Àyà Gómìnà fi kún ọ̀rọ̀ rè pé láìsí òfin tó múná dóko ko lè ṣí agbègbè tó bójú mu fún, àlàáfíà, ààbò, ati ìlera pípé

Nínú ọrọ rẹ igbakeji ọgá àgbà ilé ìwé gíga Fásítì ti Ipínlẹ̀ Cross River, Ọ̀mọ̀wé Nlerum Okogbule ni, Dandan ni kí òfin tó f’ẹsẹ múlẹ wà nipa titun agbègbè ṣe kí àṣeyọrí le wà nípa ọ̀rọ̀ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button