Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ Ọjọ́ Àyájọ́ Mọ̀ọ́kọ-Mọ̀ọ́kà

0 309

Orílẹ̀ Èdè nàìjíríà dá ìwọ́ ìdùnnú pẹ̀lú akẹgbẹ́ rẹ̀  ní àgbáyé fún ìsàmì ọjọ́ gbígbé ẹ̀kọ́ lárugẹ. Eléyìí wà fún mímọ rírì àti ipa pàtakì tí ẹ̀kọ́ ń kó láwùjọ wa, nípa ìdàgbàsókè ọrọ̀ ajé àti ìgbáyégbádùn.

 

Asojú ètò ẹ̀kọ́, ti olú ìlú Àbújá, ẹni tí alámòjútó àgbà, Leramoh Abdurasaq sojú fún, ló fi ọ̀rọ̀ náà léde wípé, ayẹyẹ ti ọdún 2022 yìí yóò se àfirinlẹ̀ ọ̀nà láti sọ ẹ̀kọ́ kíkọ́ di ànfààní fún mùtúmùwà.

 

Arábìnrin Alayande pa àrọwà fún àmúlò àwọn ibùdó tí kò dín ní igba, tí ó wà fún ètò ẹ̀kọ́  àti isé ọwọ́, láti le ìsẹ́ wọ ìgbẹ́ àti fún ètò ẹ̀kọ́ tí ó yarantí.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button