Take a fresh look at your lifestyle.

olórí ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún àwọn ọmọ ogun ní ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ Hilux tuntun gẹ́gẹ́ bíi Iṣé àkànṣe rè

0 248

Olórí Òṣìṣẹ́ ológun Nàìjíríà (COAS), Lieutenant General Faruk Yahaya ti sí ẹnu-ọ̀nà Maxwell Khobe Cantonment tí wọ́n tún ṣe, kíkọ́ ibi tí àwọn ọmọ ogun máa ń dúró sí (Quarter Guard), síṣe ọ̀nà tó ṣe tọ́ dáadáa àti fífún ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ Hilux tuntun sí ẹ̀ka Regimental Sergeant Major mẹ́ta.

COAS sọ pé àwọn iṣẹ́ àkànṣe yìí yóò mú ààbò  Cantonment nípọn si. Ó ní àwọn ọmọ ogun Naijiria yóò ríi dájú pé àwọn ohun èlò amáyédẹrùn ní báráàkì yóò di ìgbàlódé.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button