Ààrẹ Muhammadu Buhari ti kí àwọn ẹbí, àwọn ọ̀rẹ́ àti àwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ bí ó ti ń kẹ́dùn ikú Inspector-General of Police (IGP), Mustapha Balogun.
Ó tún bá àwọn ọlọpa Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà kẹ́dùn, nitori ibi ti olóògbé ti lo àkókò ti o dára jùlọ nínú ìgbésí ayé rẹ̀ nìyẹn.
Ó gbàdúrà fún ìsinmi àlááfíà fụ́n ọkàn olóògbé.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply