Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ Ọdún Iléyá: Àgbà wa náà ṣèwerí: Ààrẹ Buhari

0 244

Ààrẹ Muhammadu Buhari gbàlejò àwọn akékọ̀ọ́ kíláàsì alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama rẹ̀ tí wọ́n lọ kíí ní ìlú Daura, ní ìpínlẹ̀ Katsina láti fi sàjọyọ̀ ọdún iléyá.

Nínú ìpàdé yìí, Ààrẹ Buhari bá wọn jíròrò nípa ìlera ẹnìkọ̀ọ̀kan, àti ti awọn molẹbi wọn.

Wọ́n shàdúrà fún àwọn ọkàn tó ti dolóògbé láàrín wọn láti ọdún tó kọjá sí àkókò yìí.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button