Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ orílẹ̀ -èdè Ígípútì gba olórí-orílẹ̀-èdè Ísírélì,Ọmọ-ọba Abu Dhabi lálejò

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 288

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Ígípútì, Abdel Fattah al-Sissi, ti gba olórí orílẹ̀ Ísírẹ́lì Naftali Bennett tí ó sí tún jẹ ́ọmọ ọba Abu Dhabi  Mohammed bin Zayed.

Ipade ti o waye ni ilu igbafẹ Sinai ni Sharm el-Sheikh, da lori “paapaa lori agbara ati aabo ounje” ti  waye nitori ogun to n ṣẹlẹ ni Ukireini, gẹgẹ bi awọn oṣiṣẹ ijọba Igiputi ṣe sọ.

Ni igba akọkọ ti iru eleyi n ṣẹlẹ, ipade waye nitori ọrọ larin orilẹ-ede Irani  ati awọn alagbara pataki ni Vienna lori ọrọ eto iparun, ti Israeli  kopa ninu adehun rẹ ati orisirisi awọn  orilẹ-ede Arab, ti Igiputi ati awọn Ẹmireti jẹ ara wọn.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button