Orílẹ̀-èdè Níú sìlaǹdì yóò Pès̀e Ukiréínì Pẹ̀lú Ìrànlọ́wọ́ ológun tí kìí ṣe apànìyàn
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Orílẹ̀-èdè Níú sìlaǹdì sọ ní ọjọ́ àìkú pé òhun yóò pèsè orílẹ̀-èdè Ukiréínì pẹ̀lú iye owó NZ $ mílíọ̀nù márùn ún ($ 3.46 million) àti ìrànlọ́wọ́ ológun tí kìí ṣe apànìyàn pẹ̀lú díẹ̀ nínú ohun èlò tóṣẹ́kù sílẹ̀ tí wọn kò lò.
Prime Minisita Jacinda Ardern sọ pe, owo naa yoo jẹ sisan si apo NATO, igbimọ kan ti o n pese epo, awọn ounjẹ, ohun elo ibaraẹnisọrọ ati awọn ohun elo iranlọwọ akọkọ lati ṣe atilẹyin fun orile-ede Ukireini bi o ṣe koju ogun pẹlu orilẹ-ede Rọsia ni ọjọ kerinle-logun,oṣu kejila.
Orilẹ-ede Niu silandii ti tun paṣẹ awọn ijẹniniya lori Rọsia ti o si tun ti ṣeto iwe iwọlu pataki kan fun awọn ara ilu Ukireini.
Leave a Reply