Ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn afẹ̀hónúhàn ló tú yáyá sí ojú òpópónà ní olú-ìlú Sudan, Khartoum, tí wọ́n sì ń pè fún ìtúsílẹ̀ gbogbo àwọn tó wà láhàámọ́ àti láti tako ìfipágbàjọba àwọn ológun ní Oṣù Kẹwàá,èyí tí ó túnbọ̀ sọ orílẹ̀-èdè náà sínú rògbòdìyàn.
Awọn ologun aabo ta awọn agolo gaasi si awọn afẹhonuhan naa fun lilodi si ijọba ọhun.
Ti Diẹ ninu awọn afẹhonu han naa si n sọ awọn agolo gaasi naa pada si awọn oṣiṣẹ aabo.
Apejọ ọjọ Aje yii jẹ tuntun ninu gbogbo awọn eleyi ti wọn ti ṣe tẹlẹ lori bi ijọba ologun ṣe gbajọba lọwọ ijọba tiwantiwa.
Leave a Reply