Sultan Sa’ad Abubakar tí ó jẹ́ Sultan ìpínlẹ̀ Sokoto àti alága Ilé-ìgbìmọ̀ gíga fuń ọ̀rọ̀ to jẹ mọ́ ẹ̀sin musulumi, ti rọ àwọn Musulumi àti àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbogbo làti máa tẹ̀síwájú ní gbogbo ìgbà ní gbígbé ìṣọ̀kan àti àlááfià lárugẹ ní orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.
Sultan Sa’ad Abubakar so pe igbega alaafia ati isọkan lawujọ jẹ ọna ti o yẹ ki Musulumi maa tẹle ninu eto ilana ẹkọ wọn.
Sultan ṣe idaniloju adehun rẹ lati fọwọsowọpọ pẹlu awọn ara ilu lati le koju awọn ipenija to n koju orilẹ-ede Naijiria .

Tolulọpẹ
Leave a Reply