Wọn Yán Olumide Oyedeji Pẹ̀lú Ìbò Sí Ẹgbẹ́ Òlímpíkì Àgbáyé
Ọmọ Nàìjíríà, Olumide Oyedeji ní wọ́n tí yán gẹ́gẹ́ bí Akọ̀wé Gbogbogbò tí Ẹgbẹ́ Àwọn Òlímpíkì Agbaye.
Àtẹ̀jáde kán ní Ìpínlẹ̀ Èkó nípasẹ̀ Afolabi Oni, olùrànlọ́wọ́ ìròyìn rẹ̀, sọ pé Ó bóri Salvador Salguero ti El Salvador ati Liston…