WHO Yàn Olùdarí Àgbègbè Túntún Tí Áfíríkà
Àjọ Àgbáyé fún Ìlera (World Health Organization WHO) tí kéde yíyan tí Ọ̀jọ̀gbọ́n Mohamed Janabi gẹ́gẹ́bí Olùdarí túntún fún Ẹkùn Áfíríkà tí WHO.
Yíyan náà ni a ṣé l'àkókò àpéjọ pàtàkì kán tí Ìgbimọ Àgbègbè WHO fún Áfíríkà, tó wáyé ní…