DG VON Ṣèbẹ̀wò Sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa Fún Ìbáṣepọ̀ Ìròyìn Tó Lágbára
Olùdarí Àgbà fún Ilé Akéde Nàìjíríà (Voice of Nigeria VON), Mallam Jibrin Baba Ndace, ti ṣe ìbẹ̀wò sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa, Abdullahi Sule, ní Ilé Ìjọba ní Lafia, èyí tó ń mú kí àjọṣepọ̀ láàrín àwọn oníròyìn àgbáyé àti ìjọba ìpínlẹ̀ náà…