Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Trade Union Congress (TUC)

Ìjọba Nàìjíríà Kéde Ọjọ́ Kínní Oṣù Karùn-ún, Ọdún Yìí Fún Ìsinmi Àwọn Òṣìṣẹ́

Ìjọba Nàìjíríà tí kéde Ọjọ́bọ̀, ọjọ́ kínní oṣù kàrún, ọdún 2025 gẹ́gẹ́bí ọjọ́ ìsinmi fún gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ jákèjádò Orílẹ̀-èdè látí samisi Ayẹyẹ Ọjọ́ Àwọn òṣìṣẹ́ tí ọdún yìí. ‎ ‎ Mínísítà fún ètò abẹ́lé, Dókítà Olubunmi Tunji-Ojo, tó…

Olùdámọ̀ràn Ààbò Nàìjíríà Tí Rọ́ NLC, TUC Látí Fágilè ìdá-ìṣẹ́-sílẹ̀ Jakéjadó Orílẹ̀-èdè

Olùdámọ̀ràn fún ètò ààbò lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mallam Nuhu Ribadu, tí ro àwọn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ (NLC) àtí (TUC) látí Fágilè ìdá-ìṣẹ́-sílẹ̀ wọ́n káàkiri Orílẹ̀-èdè lásìkò tó tún bú ẹnú atẹ́ lú ikọlù Ààrẹ ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ NLC, Comrade Joe Ajaero.…
button