Ìdásílẹ̀ Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ní Yóò Fí Òpin Sí Rògbòdìyàn Ètò Ààbò – Gómìnà Sani
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani, sọ pé ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ ní yóó fí òpin sí àwọn ìpèníjà ààbò tó ń wáyé ní gbogbo àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rin-dín-logójì (36) tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Gómìnà Uba, tó sọ èyí níbí ifọrọwanilẹnuwo kán ní…