Àwọn Akọ̀ròyìn Congo pè fún ìdásílẹ̀ òṣìṣẹ́, Stanis Bujakera
Àwọn Akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè Congo ti fún ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ń mójútó ìdájọ́, ní ìwé àdéhùn fún ìbéèrè láti dá alájọṣiṣẹ́ wọn, Stanis Bujakera sílẹ̀.
Wọn mu akọroyin Ọdọ Adulawọ ati ti wọn si ti mọle ni…