Arábìnrin Àkọ́kọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Mọ́ Rírì Àwọn Àgbàlagbà
Ìyàwó Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Oluremi Tinubu, tí mọ́ rírí àwọn ìrànlọ́wọ́ tí àwọn àgbàlagbà ṣé sí àwọn ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè yìí, èyí tó fá àgbékalẹ̀ 'Renewed Hope Initiative, Elderly Support Scheme, (RHIESS).'
Ó rọ àwọn àgbàlagbà…