Ààrẹ Tinubu Ṣèpàdé Pẹ̀lú Paul Kagame Ní Paris
Ààrẹ Bola Tinubu ti ṣé ìpàdé bóǹkẹ́lẹ́ pẹ̀lú Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Rwanda, Paul Kagame, ní Paris, France, níbi tí àwọn olórí méjèèjì ti jíròrò àwọn ọrọ àgbáyé àti tí Áfíríkà.
Ìpàdé bóǹkẹ́lẹ́ náà jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ ti Ààrẹ Tinubu tí yóò…