Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí gúnlẹ̀ sí Lísíbọ̀nì, Pọ́túgàlì.
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti gúnlẹ̀ sí Lísíbọ̀nì,lórílẹ̀-èdè Pọ́túgàlì fún àbẹ̀wò.
Awọn alaṣẹ orilẹ-ede Pọtugali ati diẹ ninu awọn ọmọ Naijiria ti n gbe nibẹ ni wọn wa ki kaabọ ni papakọ ofurufu Lisibọni.
Ibẹwo…