Ọlọ́pàá Yabo Ibùdó Àwọn Ọdaràn Ní Plateau
Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Plateau tí ṣé àṣeyọrí ńláǹlà nínú gbígbógun tí ìwà ọ̀daràn, tí wọ́n sì gba òun ìjà tó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta lọ́wọ́ wọ́n lákòókò tí wọ́n yabo ibùdó àwọn ọ̀daràn kán ní ìjọba ìbílẹ̀ Àríwá Jos.
Kọmisana…