Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

People’s Democratic Party PDP

Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ Gúúsù Nìkàn Ló L’ẹ̀tọ́ Láti Díje Fún Ipò Ààrẹ – PDP

‎Ẹgbẹ́ Òṣèlú People’s Democratic Party (PDP) ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Ààrẹ tẹ́lẹ̀ Goodluck Jonathan àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mìíràn láti Gúúsù Nàìjíríà nìkàn ló l'ẹ̀tọ́ láti díje fún ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú náà nínú ìdìbò gbogbogbòò ti ọdún…
button