Ààrẹ Tinubu dárò ikú Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ nígbà kan rí, Olunloyo
Ààrẹ Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu ti ṣèdárò pẹ̀lú ìjọba àti àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Oyo lórí ikú Dókítà Victor Omololu Olunloyo, Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ àtijọ́ nígbà kan rí.
Ààrẹ Tinubu, ni orukọ Ijọba Apapọ, ti…