Ológun yóò ṣèwáádí ẹ̀sùn àìróúnjẹ jẹ àwọn ọmọ ogun tó wà lójú ogun
Ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ ológun, COAS, AjagunTaoreed Lagbaja ti pè fún ìṣèwáádí ẹ̀sùn àìróúnjẹ jẹ àwọn ọmọ ogun tó wà lójú ogun ní Gúsù ilà oòrùn.
Ninu ọrọ kan ti adari eto ibaraẹniṣepọ fun awọn ọmọ ogun,…