Ológun gba àwọn tí wọ́n jí gbé sílẹ̀
Àwọn ọmọ ologun Joint Task Force Northwest Operation HADARIN DAJI lábẹ́ Ikọ̀ kẹjọ ọmọ ológun Nàìjíríà ti gba àwọn tó wà láhàámọ́ ajínigbé méjìdín-lógún sílẹ̀ ní agbègbè tí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́, tí ó wà lábẹ́…