Ẹ má ṣiyè méjì lórí Tinubu, Okechukwu rọ ọmọ Nàìjíríà
Aĺáṣẹ àpapọ̀, Voice of Nigeria (VON), Ọ̀gbẹ́ni Osita Okechukwu, ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti ní ìgbàgbọ́ nínú ààrẹ Bọla Tinubu, fún àtúnṣe ipò ìbáraeniṣepọ̀ ọrọ̀ Ajé Nàìjíríà.
Ọgbẹni Okechukwu, oludasilẹ ọmọ…